Ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò
Ìmúdúró àwọn Aláṣẹ Gbogbogbò, Aláṣẹ Àádọ́rin Agbègbè, àti Olóyè Gbogbogbò ti Ìjọ
Ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò Oṣù Kẹ́rin 2020


Ìmúdúró àwọn Aláṣẹ Gbogbogbò, Aláṣẹ Àádọ́rin Agbègbè, àti Olóyè Gbogbogbò ti Ìjọ

Ẹ̀yin arákùnrin àti arábìnrin, èmi yíò gbé àwọn Aláṣẹ Gbogbogbò, àwọn Àádọ́rin Agbègbè, àti àwọn Olóyè Gbogbogbò Ìjọ fún ìbò ìmúdúró.

Ẹ jọ́wọ́ e fi ìbò yín hàn bí ẹ ti nṣe níbikíbi tí ẹ lè wà. Bí a bá rí àwọn wọ̀nni tí wọń tako eyikeyi nínú àwọn àbá tí a ti gbékalẹ̀, a ni kí ẹ lọ bá ààrẹ èèkan yín.

A dalaba pé kí a ṣe ìmúdúró Russell Marion Nelson bí wòlíì, aríran, àti olùfihàn àti Ààrẹ Ìjọ Jésù Kristì ti àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹhìn; Dallin Harris Oaks bí Olùdámọ̀ràn Kínní; àti Henry Bennion Eyring bí Olùdámọ̀ràn Kejì nínú Àjọ Ààrẹ Ìkinní.

Àwọn wọnnì tó bá faramọ lè fihàn.

Àwọn wọnnì tó bá tàkòó, tí ẹnikẹ́ni bá wà, lè fihàn.

A dalaba pé kí a ṣe imúdúró Dallin H. Oaks bí Ààrẹ Iyejú àwọn Àpọ́stélì Méjìlá àti M. Russell Ballard bí Aṣojú Ààrẹ Iyejú àwọn Àpọ́stélì Méjìlá.

Àwọn to bá faramọ, jọ̀wọ́ ṣàpẹrẹ.

Alátakò kankan tó bá wa lè fihàn.

A dalaba pé kí a ṣe imúdúró àwọn wọ̀nyí bí ọmọ Iyejú àwọn Àpọ́stélì Méjìlá: M. Russell Ballard, Jeffrey R. Holland, Dieter F. Uchtdorf, David A. Bednar, Quentin L. Cook, D. Todd Christofferson, Neil L. Andersen, Ronald A. Rasband, Gary E. Stevenson, Dale G. Renlund, Gerrit W. Gong, àti Ulisses Soares.

Àwọn tó bá faramọ, jọ̀wọ́ fihàn.

Alátakò kankan lè ṣe àmì bẹ́ẹ̀.

A dalaba pé kí a ṣe ìmúdúró àwọn olùdámọ̀ràn nínú Àjọ Ààrẹ Ìkínní àti Iyejú àwọn Àpọ́stélì Méjìlá bí àwọn wòlíì, aríran, àti olùfihàn.

Gbogbo ẹni tó bá faramọ, jọ̀wọ́ fihàn.

Ìlòdì, bí èyíkéyi bá wá, nípa irú àmì kannáà.

A dalaba kí a dá àwọn wọ̀nyí sílẹ̀ bí àwọn Áádọ́rin Agbègbè: Àwọn Alàgbà Jorge T. Becerra, Mark S. Bryce, Jeremy R. Jaggi, Kelly R. Johnson, Adeyinka A. Ojediran, àti Moisés Villanueva.

Àwọn wọnnì tí wọ́n fẹ́ láti darapọ̀ mọ́ wa ní fífi ìmoore hàn sí àwọn arákùnrin wọ̀nyí fún iṣẹ́ ìsin wọn tó tayọ, jọ̀wọ́ fihàn.

A dalaba pé kí a dá àwọn Àjọ Ààrẹ wọ̀nyí sílẹ̀ pẹ̀lú ìmoore: Stephen W. Owen bi Ààrẹ, Douglas D. Holmes Olùdámọ̀ràn Kínní, àti M. Joseph Brough bí Olùdámọ̀ràn Kejì.

Àwọn wọnnì tí wọ́n fẹ́ láti darapọ̀ mọ́ wa ní fífi ìmoore hàn sí àwọn arákùnrin wọ̀nyí fún iṣẹ́ ìsin alárà, jọ̀wọ́ fihàn.

A dalaba kí a ṣe ìmúdúró àwọn Aláṣẹ Gbogbo wọ̀nyí: Jorge T. Becerra, Matthew S. Holland, William K. Jackson, Jeremy R. Jaggi, Kelly R. Johnson, Thierry K. Mutombo, Adeyinka A. Ojediran, Ciro Schmeil, àti Moisés Villanueva.

Gbogbo ẹni tó bá faramọ, jọ̀wọ́ fihàn.

Àwọn alátakò, nípa irú àmì kannáà.

A dalaba kí a ṣe ìmúdúró àwọn Àádọ́rin Agbègbè wọ̀nyí: Jay D. Andersen, Faapito Auapaau, Frederick K. Balli Jr., Kevin W. Birch, John W. Boswell III, J. Francisco Bührer, Suchat Chaichana, Matthew R. Clarke, L. Guido Cristobal, Edmarc R. Dumas, Carlos A. Gabaldón, M. Andrew Galt IV, Clark G. Gilbert, Leonard D. Greer, Vladislav Y. Gornostaev, D. Martin Goury, Richard I. Heaton, Broc C. Hiatt, David H. Huntsman, Norman C. Insong, Daniel Kabason, Federico M. Kähnlein, Jeffrey J. Kerr, Youngjoon Kwon, David G. LaFrance, Ricardo C. Leite, Marcelo Louza, Jose G. Manarin, Jeremiah J. Morgan, Mark A. Mortensen, Eduardo F. Ortega, Nathan D. Pace, Michael M. Packer, Omar I. Palacios, Jorge W. Pérez, Kyrylo Pokhylko, Sergio A. Poncio, Arthur Rascon, Miguel A. Reynoso, Gustavo G. Rezende, Robert G. Rivarola, Tonga J. Sai, Luciano Sankari, Rosendo Santos, Henry Savstrom, J. Matthew Scott, James E. Slaughter, Robert T. Smith, Ricardo A. Spencer, Colin C. Stauffer, David C. Stewart, Jared W. Stone, Arlen M. Tumaliuan, Martin J. Turvey, Yan C. Vega, Paul B. Whippy, Chad R. Wilkinson, àti Dow R. Wilson.

Gbogbo ẹni tó bá faramọ, jọ̀wọ́ fihàn.

Àwọn alátakò, to báwa.

A dalaba kí a ṣe ìmúdúró àwọn Àjọ Ààrẹ Gbogbogbò Steven J. Lund bí Ààrẹ, Ahmad Saleem Corbitt bí Olùdámọ̀ràn Kínní, àti Bradley Ray Wilcox bí Olùdámọ̀ràn Kejì.

Àwọn wọnnì tó bá faramọ lè fihàn.

Alátakò kankan lè ṣe àmì bẹ́ẹ̀.

A dalaba pé kí a ṣèmúdúró àwọn Aláṣẹ Gbogbogbò, Àádọ́rin Agbègbè, àti àwọn Olóyè Gbogbogbò bí a ṣe gbé wọn kalẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́.

Gbogbo ẹni tó bá faramọ, jọ̀wọ́ fihàn.

Àwọn alátakò, to báwa.

Lẹ́ẹ̀kansi, a pe àwọn wọnnì tí wọ́n lè tako èyíkéyi nínú àbá wọ̀nyí láti rí àwọn ààrẹ èèkan.

A dúpẹ́ lọ́wọ́ yín fún ìtẹ̀síwájú ìgbàgbọ́ yín àti àdúrà ní ìtìlẹhìn àwọn olórí Ìjọ.

Tẹ̀