Ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò Oṣù Kẹ́rin 2020 Abala Òwúrọ̀ Sátidé Abala Òwúrọ̀ Sátidé Russell M. NelsonỌ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀Ààrẹ Nelson kọ́ni pé bí a ti ndàbí Olùgbàlà wa si, a lè ní àláfíà àti ayọ̀ àní ní àwọn ìgbà ìṣòrò. M. Russell BallardNjẹ́ A Kì Yío Ha Tẹ̀síwájú ninu Iṣẹ́ Nlá Yi?Ààrẹ Ballard ṣàpèjúwé òtítọ́ àti ìrúbọ Josèh Smith àti arákùnrin rẹ̀ Hyrum. James R. RasbandMímú Ìdájọ́ Òdodo DájúAlàgbà Rasband kọ́ni bí Ètùtù Krísti ṣe mú ìdáláre àti àánú wá sí ìmúṣẹ. Joy D. JonesỌ̀kan Pàtàkì Ìpè Ẹni-ỌláArábìnrin Jones fà lórí àpẹrẹ Joseph Smith tí ó gba àwọn obìnrin níyànjú nípa títíraka láti mú ipa ẹ̀mí nla wọn ṣẹ. Neil L. AndersenÀwọn Ìránti Onítumọ̀ Ti Ẹ̀míAlàgbà Andersen kọ́ni pé rírántí àwọn àkokò ìrántí onítumọ̀ ti ẹ̀mí nínú ayé wa lè fún wa lókún àti ìtùnú ní àwọn ìgbà ìpènijà. Douglas D. HolmesJinlẹ̀ Nínú Ọkàn WaAràkùnrin Holmes kọ́ni wa làti dojúkọ ìbáṣepọ̀, ìfihàn, agbára lati yàn, ìrònúpìwàdà, àti ìrúbọ kí ìhìnrere le wọnú ọkàn wa jinlẹ̀jinlẹ̀. Henry B. EyringÀdúrà Ìgbàgbọ́Ààrẹ Eyring kọ́ni bí gbígbàdúrà nínú ìgbàgbọ́ fi lè rànwálọ́wọ́ láti rí ojúṣe àrà wa ní Ìmúpadàbọ̀sípò tó nlọ lọ́wọ́. Abala Ọ̀sán Sátidé Abala Ọ̀sán Sátidé Dallin H. OaksÌmúdúró àwọn Aláṣẹ Gbogbogbò, Aláṣẹ Àádọ́rin Agbègbè, àti Olóyè Gbogbogbò ti ÌjọÀàrẹ Oaks gbé ìbò ìmúdúró kalẹ̀ fún àwọn olórí Ìjọ. Kevin R. JergensenÌròhìn Ẹ̀ka Jíjẹ́rí Ìṣírò owó Ìjọ, Ọdún 2019Arákùnrin Jergensen gbé ìròhìn Ẹ̀ká ìjẹ́ẹ̀rí ìṣirò owó fún 2019 kalẹ̀. Ulisses SoaresJíjádewá ti Ìwé Mọ́mọ́nìAlàgba Soares ṣe àpèjúwe púpọ̀ àwọn iṣẹ́ ìyanu tí ó wà nínú jíjádewá ti Ìwé Mọ́mọ́nì, pẹ̀lú àwọn iṣẹ́ ìyanu t ó le ṣẹlẹ̀ nínú ìgbé ayé wa nítorí àkọsílẹ̀ mmọ́ yi John A. McCuneẸ wá sí ọ̀dọ̀ Krístì—Gbígbé bí Àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́ ÌkẹhìnAlàgbà McCune kọ́ wa bí ìhìnrere Jésù Krístì tí a mú padàbọ̀sípò ṣe nrànwá lọ́wọ́ láti ṣe àwọn ohun tí ó ṣòro kí ẹ sì ran àwọn ẹlòmíràn lọ́wọ́ láti ṣe bákannáà. Gérald CausséAlààyè Ẹlẹ́ri kan ti Krístì AlààyèBíṣọ́ọ̀pù Caussé kọ́ni pé Ìwé ti Mọ́mọ́nì mú ìmọ̀ òtítọ́ padàbọ̀sípò nípa Jésù Krístì àti Ètùtù Rẹ̀. Dale G. RenlundRonú Nípa Ìṣerere àti Títóbi Ọlọ́runAlàgbà Relund pè wá láti rántí ìwàrere àti títóbijùlọ Bàbá Ọ̀run àti Jésù Krístì àti kí a fi onírurú ìbùkún hàn ní ṣiṣe bẹ́ẹ̀. Benjamin M. Z. TaiAgbára Ìwé ti Mọ́mọ́nì nínú ÌyípadàAlàgbà Tai kọ́ni pé Ìwé ti Mọ́mọ́nì ní ẹkọ́ Krístì nínú ó sì nrànwá lọ́wọ́ láti súnmọ́ Ọlọ́run si. Gary E. StevensonÌpìlẹ̀ Rere Kan sí Ìgbà tí ó Nbọ̀Alàgbà Stevenson kọ́ bí àwọn ìlọsíwájú Tẹ́mpìlì Salt Lake ṣe là ràn ìmísí wa lọ́wọ́ láti kọ àwọn ìpìlẹ̀ araẹni ti o lágbára. Abala Ìrọ̀lẹ́ Sátidé Abala Ìrọ̀lẹ́ Sátidé Gerrit W. GongHosanna àti Hallelúyà—Jésù Krístì Alààyè: Ọkàn Ìmúpadàbọ̀sípò àti Ọdún ÀjíndeAlàgbà Gong kọ́ni bí Jésù Krístì ṣe jẹ́ ọkàn Ọdún Àjínde àti ìmúpadàbọ̀sípò ti ọjọ́ ìkẹhìn. Laudy Ruth Kaouk AlvarezBí Oyè Àlùfáà ti Nbùkún Ọ̀dọ́Arábìnrin Kaouk kọ́ni bí àwọn ọ̀dọ́ ṣe lè di alábùkúnfún nípasẹ̀ oyèàlùfáà. Enzo Serge PeteloBí Oyè Àlùfáà ti Nbùkún Ọ̀dọ́Arákùnrin Petelo kọ́ni bí iṣẹ́ ìsìn ti oyèàlùfáà ti le bùkún àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin. Jean B. BinghamÌdàpọ̀ ní Àṣeyọrí Iṣẹ́ Ọlọ́runArábìnrin Bingham kọ́, bí títẹ̀lé àpẹrẹ Ádámù àti Éfà, àwọn ọkùnrin ati obìnrin lè ṣiṣẹ́ papọ̀ láti mọ ìyàtọ̀ àti ipò ti ẹ̀mí ara wọn. Henry B. EyringÓ Nlọ Ṣíwájú WaÀàrẹ Eyring kọ́ni pé Olúwa mọ ọjọ́ Ọ̀la Ó sì ndarí wa, lẹsẹẹsẹ, láti ṣe àṣeyege àwọn èrò rẹ̀ ní àwọn ọjọ́ ìkẹhìn náà. Dallin H. OaksOyèàlùfáà Mẹlkisèdèkì àti àwọn Kọ́kọ́rọ́ Rẹ̀Ààrẹ Oaks kọ́ni nípa iṣẹ́ ṣíṣe oyèàlùfáà nínú Ìjọ àti nínú ilé. Russell M. NelsonṢíṣí Ọ̀run fún Ìrànlọ́wọ́Ààrẹ Nelson fi ìwò titun olùjúwe fún Ìjọ hàn ó sì pe gbogbo ènìyàn láti gbàwẹ̀ àti àdúrà. Abala Àárọ̀ Ọjọ́ Ìsinmi Abala Àárọ̀ Ọjọ́ Ìsinmi Ronald A. RasbandÌmúṣẹ nípa Àsọtẹ́lẹ̀Alàgbà Rasband kọ́ni nípa àwọn àsọtẹ́lẹ̀ tí a ti múṣẹ nínú Ìmúpadàbọ̀sípò Ìjọ tó nlọ lọ́wọ́. Bonnie H. CordonPé Kí Wọ́n Lè RiSister Bonnie D. Cordon pe gbogbo wa lati tẹ̀lé àpẹrẹ Jésù Krístì kí a si jẹ́ ìmọ́lẹ̀ àti àpẹrẹ fún àwọn ti o yi wa ka. Jeffrey R. HollandÌmọ́lẹ̀ Pípé ti Ìrètí KanAlàgbà Holland kọ́ni pé Ìmúpadàbọ̀sípò ìhìnrere fihàn pé a lè ní ìrètí nítorí Ọlọ́run wà pẹ̀lú wa. David A. BednarẸ Jẹ́ Kí Ilé Yí Di Kíkọ́ Sí Orúkọ MiAlàgbà Bednar kọ́ni pé àwọn ìlànà àti májẹ̀mú tẹ́mpìlì nyí ọkàn wa padà ó sì nbùkún àwọn ẹbí ní ẹ̀gbẹ́ méjèèjì ìbòjú. Russell M. NelsonGbọ́ Tirẹ̀!”Ààrẹ Nelson kọ́ni pé a lè gbọ́ Olúwa, ó sì gbé ìpolongo titun kan jáde: “Ìmúpadàbọ̀sípò Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ Ìhìnrere Jésù Krístì: Ìpolongo Igba Ọdún Kan Sí Àgbáyé.“ Russell M. Nelson(Igbe Hòsánnà)Ààrẹ Nelson darí àwọn olùkópa nínú Igbe Hòsánnà mímọ́ ní ṣíṣayẹyẹ Ìran Àkọ́kọ́ ti Bàbá àti Ọmọ. Abala Ọ̀sán Ọjọ́ Ìsimi Abala Ọ̀sán Ọjọ́ Ìsimi Dallin H. OaksÈtò NláÀàrẹ Oaks kọ́ni ní àwọn kókó ohun èlò ètò ti Bàbá Ọ̀run, pẹ̀lú ìdánilójú mẹ́rin tí o´ fún wa ní ayé ikú. Quentin L. CookÌbùkún ti Ìtẹ̀síwájú Ìfihàn sí àwọn Wòlíì àti Ìfihàn Araẹni sí Ìtọ́nisọ́nà Ìgbé Ayé WaAlàgbà Cook kọ́ni pé a`wọn wòlíì tẹ̀síwájú láti gba ìfihàn láti tọ́ Ìjọ sọ́nà ati pé kí a lè gba ìfihàn láti tọ́ ìgbé ayé wa sọ́nà. Ricardo P. GiménezRírí Ààbò kúrò nínú àwọn Ìjì AyéAlàgbà Giménez kọ́ni pé Krístì le jẹ́ ààbò kúrò lọ́wọ́ ọ̀tá àti àwọn ìjì inú ayé wa bí a bá fi ààyè gbà Á. Dieter F. UchtdorfWá kí o sì Wà Pẹ̀lúAlàgbà Uchtdorf pe gbogbo ènìyàn pé ẹ pẹ̀lú wa, ní ṣíṣe ìránṣẹ́ sí àwọn ọmọ Ọlọ́run, ní títẹ̀lé ipa ẹsẹ̀ Olùgbàlà, kí a si ṣe ayé yí ní ibi dídára. L. Whitney ClaytonÀwọn Ibùgbé Dídára JùlọAlàgbà Clayton kọ́ni pé a di dídárájùlọ arawa bí a ṣe ntiraka láti gbé ìgbé ayé ìmúpadàbọ̀sípò ìhìnrere Jésù Krístì. D. Todd Christofferson Pípín Ọ̀rọ̀ Ìmúpadàbọ̀sípò àti ÀjíìndeAlàgbà Christofferson kọ́ni nípa pàtàkì pípín ọ̀rọ̀ Ìmúpadàbọ̀sípò ó sì fúnni ní àwọn ohun mẹ́ta tí a nílò láti ṣe bẹ́ẹ̀ ní àṣeyege. Russell M. NelsonLọ Síwájú nínú Ìgbàgbọ́Ààrẹ Nelson kọ́ni pé a o gba okun bí a ṣe njẹ́ akọni olùtẹ̀lé Jésù Krístì àti bí a ṣe nbọ̀wọ̀ fún àwọn májẹ̀mú wa. Ó kéde àwọn tẹ́mpìlì titun.