Ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò Oṣù Kẹ́rin 2021 Abala Òwúrọ̀ Sátidé Abala Òwúrọ̀ Sátidé Russell M. NelsonỌ̀rọ̀ Ìkíni Káàbọ̀Ààrẹ Nelson kí wa káàbọ̀ sí ìpàdé àpapọ̀ gbogbogbò, ṣe àkíyèsí bí Olúwa nyára sí iṣẹ́ Rẹ̀, Ó sì pè wá láti mú ìdọ̀tí kúrò nínú ayé wa kí a lè di yíyẹ si. Dieter F. UchtdorfỌlọ́run Láarín WaAlàgbà Uchtdorf kọ́ wa láti ní ìrètí, kì a ma ṣe aláìnírètí, kí a sì rí àwọn ọ̀nà nínú èyí tí Ọlọ́run fi wà ní àárín wa. Joy D. JonesÀwọn Ìbáraẹnisọ̀rọ̀ PàtàkìArábìnrin Jones tẹnumọ́ pàtàkì ìkọ́ni ìhìnrere Jésù Krístì sí àwọn ọmọ wa. Jan E. NewmanKíkọ́ni ní Ọ̀nà ti OlùgbàlàArákùnrin Newman tun pàtàkì kíkọ́ni bíiti Olùgbàlà nínú Ìjọ àti ilé wa sọ. Gary E. StevensonỌkàn Ìṣọ̀kan Làpapọ̀Alàgbà Stevenson kọ́ni ní pàtàkì inúrere, ìfẹ́, àti ọ̀wọ̀, fífún àwọn ọmọ, ọ̀dọ́, àti àgbà ní àmọ̀ràn pàtó. Gerrit W. GongYàrá ní Ilé ÈròAlàgbà Gong kọ́ni pé Olùgbàlà pè wá láti jẹ́ Ará Samáríà rere tí ó kí gbogbo ènìyàn káàbọ̀ sí ilé-èrò Rẹ̀ (ní títúmọ̀ sí Ìjọ Rẹ̀), níbití a ti lè rí ààbò. Henry B. EyringMo Fẹ́ láti Rí Tẹ́mpìlìÀàrẹ Eyring jẹri nípa àwọn ìbùkún ti ẹ̀mí tí ó nwá sọ́dọ̀ àwọn ẹni tí wọ́n sìn nínú tẹ́mpìlì. Abala Ọ̀sán Sátidé Abala Ọ̀sán Sátidé Dallin H. Oaks Ìmúdúró àwọn Aláṣẹ Gbogbogbò, Àádọ́rin Agbègbè, àti Olóyè GbogbogbòÀàrẹ Oaks ṣè àgbékalẹ̀ àwọn Aláṣẹ Gbogbogbò, Àádọ́rin Agbègbè, àti Olóyè Gbogbogbò kalẹ̀ fún ìbò ìmúdúró. Jared B. LarsonÌròhìn Ẹ̀ka Jíjẹ́rí Ìṣírò Owó Ìjọ, Ọdún 2020Jared B. Larson gbé ìròhìn Ẹ̀ká ìjẹ́ri ìṣirò owó fún 2020 kalẹ̀. Jeffrey R. HollandKìí ṣe bí Ayé Tií FunniAlàgbà Holland kọni pé a lè rí àláfíà nínú Krístì, àní ní àárín rògbòdìyàn àti ìjà. Jorge T. BecerraÀwọn Tálákà KékeréAlàgbà Becerra kọ́ni ní pàtàkì bíbójútó ara wa àti gbígba pé gbogbo wa ni a níló ní ìjọba Ọlọ́run. Dale G. RenlundÎbínú ÀìṣòdodoAlàgbà Relund kọ́ni pé a kò níláti jẹ́ kí àìdára mú wa ní ìkoro tàbí mú ìgbàgbọ́ wa ṣókùnkùn ṣùgbọ́n kí a bèèrè fún ìrànlọ́wọ́ lọ́dọ̀ Ọlọ́run kí a sì mú ìgbẹ́kẹ̀lé lórí Olùgbàlà pọ̀ si. Neil L. AndersenÌrìnàjò Araẹni ti Ọmọ Ọlọ́runAlàgbà Andersen kọ́ni pé àwọn ọmọ ẹ̀mí Ọlọ́run wá sí ilẹ̀ ayé lórí ìrìnàjò araẹni tiwọn àti pé a gbọ́dọ̀ kí wọn káàbọ̀, dá ààbò bò wọ́n, àti nifẹ wọn. Thierry K. MutomboẸ̀yin Yíò Di ÒmìniraAlàgbà Mutombo kọ́ni pé Jésù Krístì ni Ìmọ́lẹ̀ Ayé àti pé Ó lè tọ́wasọ́nà nínú àwọn ìgbà wàhálà àti òkùnkùn. M. Russell BallardÌrètí nínú KrístìÀàrẹ Ballard pín àwọn kókó ẹ̀kọ́ ìpìlẹ̀ marun tí ó lè ran ẹnikẹ́ni tí ó danìkan wa lọ́wọ́, pẹ̀lú àwọn ẹnití wọ́n jẹ́ ọ̀kanṣoṣo, rí ìrètí nínú Jésù Krístì. General Priesthood Session General Priesthood Session Quentin L. CookÀwọn Bíṣọ́ọ̀pù—Àwọn olùṣọ́-àgùtàn lórí Agbo OlúwaAlàgbà Cook kọ́ni nípa bí àwọn bíṣọ́ọ̀pù ṣe nṣètọ́jú fún àwọn ọmọ ìran tó ndìde nínú wọ́ọ̀dù wa. Ahmad S. CorbittẸ Le Kó Ísráẹ́li Jọ.Arákunrin Corbitt kọ́ni pé àwọn ọ̀dọ́ Ìjọ lè ṣèrànwọ́ láti kó Ísáráẹ́lì jọ bíwọ̀n ṣe lóye ìdánimọ̀ òtítọ́ àtì agbára àìláfiwé wọn. S. Gífford NielsenÀkókò Wa Nìyí!Alàgbà Nielsen rán wa létí pé a lè nígboyà nínú èrò pé a ránwa wá síbí látọ̀dọ̀ Baba Ọ̀run ní àkokò onípinnu yí nínú àkọọ́lẹ̀ ìtàn ní ètò láti mú èrèdí Rẹ̀ ṣẹ. Henry B. EyringFi ìbùkún fún ní Orúkọ Rẹ̀Ààrẹ Eyring kọ́ àwọn olùdìmú oyè-àlùfáà pé èrèdí fún gbígba oyè-àlùfáà wọn ni láti bùkún àwọn ènìyàn ní ìtilẹhìn Olúwa àti ní orúkọ Rẹ̀, gbígbé àwọn ìpè wọn ga pẹ̀lú ìfẹ́ àti aápọn. Dallin H. OaksKínni Olùgbàlà Wa Ti Ṣe fún Wa?Ààrẹ Oaks kọ̀ni pé Jésù Krístì mu ṣeéṣe fún ẹnìkọ̀ọ̀kan wa láti padà sọ́dọ̀ Baba wa Ọ̀run kí a sì ṣe àṣeyege àyànmọ́ ayérayé wa. Russell M. NelsonOhun ti A Nkọ́ tí A Kò Sì Ní Gbàgbé LaéÀàrẹ Nelson kọni ní àwọn ẹ̀kọ́ mẹrin tí ó nírètí pé a ti kọ́ nípasẹ̀ àjàkálẹ̀ àrùn. Abala Àárọ̀ Ọjọ́ Ìsinmi Abala Àárọ̀ Ọjọ́ Ìsinmi Ulisses SoaresJésù Krístì: Olùtọ́jú Ẹ̀mí WaAlàgbà Soares kọ́ni nípa Jésù Krístì, Ètùtù Rẹ̀, àti ẹ̀bùn ìrònúpìwàdà. Reyna I. AburtoIsà Òkú Kò Ní Ìṣẹ́gunArábìnrin Aburto jẹri nípa Àjínde Jésù Krístì àti pé Ètùtù Rẹ̀ ràn wá lọ́wọ́ láti borí ìkorò kí a sì rí ìrètí. S. Mark PalmerÌbànújẹ́ Wa Yìo Yípadà sí Ayọ̀Alàgbà Palmer jẹri nípa Àjínde ó sì pín bí àwọn òbí rẹ̀ ṣe darapọ̀ mọ́ Ìjọ. Edward DubeÌlépa Dé Òpin Iré-ìjeAlàgbà Dube gbà wá níyànjú láti dojúkọ ìfojúsùn wa nípa ìyè ayérayé pẹ̀lú Ọlọ́run, èyíówù àwọn ìpènijà tí ayé lè mú wá. José A. TeixeiraRántí Ọ̀nà Rẹ Padà SíléAlàgbà Teixeira kọ́ni ní pàtàkì tìtẹ̀lé Olùgbàlà bí a ṣe nṣiṣẹ́ síwájú pípadà sí ìlé wa tọ̀run. Taniela B. WakoloỌlọ́run Fẹ́ràn Àwọn Ọmọ Rẹ̀Alàgbà Wakolo jẹri nípa ìfẹ́ Ọlọ́run ó sì júwe bí Ó ṣe nfi ìfẹ́ náà hàn sí àwọn ọmọ Rẹ̀. Chi Hong (Sam) WongWọn Kò Le Borí, A Kò Le ṢubúAlàgbà Wong kọ́ni pé a kò lè ṣubú bí a bá dúró lórí ìpìlẹ̀ Jésù Krístì. Michael John U. TehOlùgbàlà ti Araẹni WaAlàgbà Teh kọ́ni ní pàtàkì mímọ̀ nípa Olùgbàlà àti ìmoore Ètùtù Rẹ̀ ní ipò araẹni. Russell M. NelsonKrístì Jínde; Ìgbàgbọ́ nínú Rẹ̀ Yíò Ṣí àwọn ÒkèÀàrẹ Nelson jẹri nípa agbára ìgbàgbọ́ nínú Jésù Krístì láti ràn wá lọ́wọ́ láti borí àwọn ìpènijà ayé. Ó daba àwọn ọ̀nà marun láti gbèrú sínú ìgbàgbọ́ alágbára jùlọ. Abala Ọ̀sán Ọjọ́ Ìsimi Abala Ọ̀sán Ọjọ́ Ìsimi Dallin H. OaksDídáàbò Bo Òfin-Orílẹ̀èdè Onímísí Àtọ̀runwáÀàrẹ Oaks ṣe àpèjúwe àwọn ẹ̀kọ́ ìjìlẹ̀ onímísí àtọ̀runwá nínú Òfin-orílẹ̀ èdè United States. Ó kọ́ni bí àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹhìn ṣe lè dá ààbò bo àwọn ẹ̀kọ́ ìpìlẹ̀ wọ̀nyí. Ronald A. Rasband“Kíyèsi! Èmi ni Ọlọ́run ÌyanuAlàgbà Rasband jẹri pé iṣẹ́ ìyanu ntẹ̀síwájú láti bùkún àwọn ọmọẹ̀hìn Jésù Krístì, gẹ́gẹ́bí ìgbàgbọ́ wa àti ìfẹ́ Ọlọ́run. Timothy J. DychesÌmọ́lẹ̀ Fi Ara Mọ́ Ìmọ́lẹ̀Alàgbà Dyches kọ́ni pé Jésù Krístì ni Ìmọ́lẹ̀ àti Ìyè Ayé àti orísun ìdùnnú òtítọ́ àti àláfíà. D. Todd ChristoffersonKínìdí Ipá Ọ̀nà Májẹ̀múAlàgbà Christofferson ṣàpèjúwe àwọn èròjà márun ohun tí ó túmọ̀ sí láti wà ní ipa ọ̀nà májẹ̀mú ó sì gbà wá níyànjú láti gbọ́ ìpè tí wòlíì láti dúró lójú ipa ọna naa. Alan R. WalkerÌmọ́lẹ̀ Ìhìnrere ti Òtítọ́ àti Ìfẹ́Alàgbà Walker kọ́ni pé iṣẹ́ Ọlọ́run nlọsíwájú ní ìyára kánkán ní àwọn ọjọ́ ìkẹhìn. David A. BednarÀwọn Ẹ̀kọ́ Ìpìlẹ̀ ti Ìhìnrere MiAlàgbà Bednar kọ́ni pé àwọn ẹ̀kọ́ ìpìlẹ̀ ìhìnrere pípé nrànwálọ́wọ́ láti ṣe àwọn àṣàyàn ọlọgbọ́n àti làti dúró lórí ipá ọ̀nà májẹ̀mú. Russell M. NelsonCOVID-19 àti àwọn Tẹ́mpìlìÀàrẹ Nelson sọ̀rọ̀ nípa ṣíṣí padà àwọn tẹ́mpìlì ó sì kéde àwọn ètò láti kọ́ àọn tẹ́mpìlì titun.